Ìfẹ-ìtumọ̀-lójú: Wíwá Ọ̀rọ̀-Ìperí Fún Àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-Ara (KASA) àti Èbólà
Ọ̀pọ̀ ọ̀ nà ni àwọn onímọ̀ ti dá lábàá fún síṣe àwárí tàbí ìṣẹ̀ dá ọ̀ rọ̀ -ìperí nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni ìsàlàyé, ìhun-ọ̀rọ̀-pọ̀ , ìfisàpẹrẹ, ìlòwe, ọ̀ rọ̀ -àyálò, ìfẹ[1]ìtumọ̀ -lójú àti bẹ́ ẹ̀ bẹ́ ẹ̀ lọ. Ìfẹ-ìtumọ̀ lójú ni ó jẹ ìwádìí yìí lógún nípa wíwá ọ̀ rọ̀ ìperí fún àrùn Kòkòrò-Apa-Sójà-A...
Saved in:
| Main Author: | |
|---|---|
| Format: | Article |
| Language: | English |
| Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
| Series: | Yoruba Studies Review |
| Online Access: | https://journals.flvc.org/ysr/article/view/130095 |
| Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|