Ògún: Bí a ṣe Fi Hàn Nínú Lítíréṣọ ̀
Ìtàn àbàláyé àwa Yorùbá sọ fún wa pé ògún ló ṣaájú gbogbo àwọn òrìsà yòókù nígbà tí wó n ń ti ìko ̣ ̀ lé o ̣ ̀ run bo ̣ ̀ wáyé. Òun ló ní àdá ti ó fi gán o ̣ ̀ nà ti ̣ gbogbo wó n gbà. Nítorí ìdí èyí, gbogbo àwọn irúnmale ̣ ̀ náà pẹnu po ̣ ̀ l...
Saved in:
| Main Author: | |
|---|---|
| Format: | Article |
| Language: | English |
| Published: |
LibraryPress@UF
2021-12-01
|
| Series: | Yoruba Studies Review |
| Online Access: | https://journals.flvc.org/ysr/article/view/130106 |
| Tags: |
Add Tag
No Tags, Be the first to tag this record!
|
| Summary: | Ìtàn àbàláyé àwa Yorùbá sọ fún wa pé ògún ló ṣaájú gbogbo àwọn òrìsà yòókù nígbà tí wó n ń ti ìko ̣ ̀ lé o ̣ ̀ run bo ̣ ̀ wáyé. Òun ló ní àdá ti ó fi gán o ̣ ̀ nà ti ̣ gbogbo wó n gbà. Nítorí ìdí èyí, gbogbo àwọn irúnmale ̣ ̀ náà pẹnu po ̣ ̀ láti yan ̣ Ògún ni ọṣìnmalè , èyí ni olórí àwọn ìmọle ̣ ̀ , nígbà tí wo ̣ ́ n dé Ilé-Ife ̣ ̀ . Ṣùgbo ̣ ́ n ̣ ògún kò rójú jókòó sojú kan láti jẹ ọlá ti a dá a nítorí ìgbé ayé líle ti ó ti mó ọ ̣ lára àti iṣé ọdẹ tí ó ń ṣe. A gbo ̣ ́ pé èyí ló gbé Ògún de Ìrè. Nígbà ti yóò so ̣ ̀ kale ̣ ̀ ̣ láti orí òkè wọ ìlú Ìrè, kòṣẹ ni:
Ọjó ògún ń ti orí òkèe bo ̣ ̀ ̣ Aṣọ iná ló mú bora Èwù e ̣ ̀ jẹ ̀ ló wo ̣ ̀ . |
|---|---|
| ISSN: | 2473-4713 2578-692X |